Yoruba edit

Pronunciation edit

  • IPA(key): /ɡ͡bá.ɡũ̄.ɡ͡bà.ɡũ̄/

Ideophone edit

gbágungbàgun

  1. (of an object) uneven; rugged; rough
    Synonyms: kángunkàngun, págunpàgun
    Kò fi bẹ́ẹ̀ jìnnà, ṣùgbọ́n ọ̀nà rí gbágungbàgun.It's not that far, but the road is bumpy.