Yoruba edit

Etymology edit

From omi (water) +‎ inú (insides, stomach)

Pronunciation edit

Noun edit

ominú

  1. (idiomatic, often in the plural) reservation, doubt
    Synonym: iyèméjì
    ominú kọ mí lórí ọ̀rọ̀ yìí
    I have some reservations on this matter
  2. regret, remorse
    Synonyms: àbámọ̀, jẹ̀ka