Yoruba edit

Etymology edit

From ibi (place) +‎ òmíràn (other).

Pronunciation edit

  • IPA(key): /ī.bò.mĩ́.ɾã̀/

Noun edit

ibòmíràn

  1. another place, somewhere else
    Synonym: ibòmíì
    Ẹ bá mi gbé iṣu yẹn sí ibòmíràn.Help me carry that yam somewhere else.

Derived terms edit