Yoruba

edit
 
Abo adìyẹ kan pẹ̀lú ọmọ rẹ̀

Etymology

edit

From abo (female) +‎ adìyẹ (chicken)

Pronunciation

edit
  • IPA(key): /ā.bō ā.dì.jɛ̄/

Noun

edit

abo adìyẹ

  1. hen
    Synonyms: àgbébọ̀, obídìẹ
    Abo adìyẹ yẹn yín ẹyin púpọ̀ lọ́sẹ̀ tó kọjá yìíThe hen laid a lot of eggs this last week
edit