ẹrọ amuletutu

Yoruba

edit
 
Àwọn ẹ̀rọ amúlétutù líta ilé ńlá onílé-ìgbé fún ọlọ́danni kọ̀ọ̀kan

Etymology

edit

ẹ̀rọ (machine) +‎ a (one who) +‎ (to have an affect on) +‎ ilé (house, home) +‎ tutù (cool), literally Machine that cools the home

Pronunciation

edit
  • IPA(key): /ɛ̀.ɾɔ̄ ā.mṹ.lé.tū.tù/

Noun

edit

ẹ̀rọ amúlétutù

  1. air conditioner