Yoruba edit

Etymology edit

From oní- +‎ ère +‎ dère

Pronunciation edit

  • IPA(key): /ē.lé.ɾē.dè.ɾē/

Noun edit

eléredère

  1. (Àkúrẹ́) perfect, beautiful; something perfectly shaped
    Kín bá ti mọ fọ̀, Ùgbèyìn nọ́n tị́ ị jọba, màá tètè yáyà. Màá mádé eléredère kọ̀n, dórí mi ooooo
    If I had known that it was in Ugbeyin that reign as king, I would have quickly went there. And I shall take a beautiful crown, and put it on my head
    (oríkì of Odò-Ùgbèyìn, a historic neighborhood in the town of Ìlárá-Mọ̀kín)