See also: Gbe, GBE, gbe-, gbẹ, and gbɛ

Gun edit

Etymology edit

Compare Saxwe Gbe ogbè, Fon gbè, Aja egbe, Ewe gbe

Pronunciation edit

Noun edit

gbè

  1. language

Derived terms edit

Mwan edit

Noun edit

gbe

  1. son

Yoruba edit

Alternative forms edit

Etymology 1 edit

Pronunciation edit

Verb edit

gbé

  1. (transitive) to carry; to lift
    Gbígbé ni mo gbé e.The fact is that I carried it.
    Ràkúnmí ò lè gbé ẹrù yín, ẹ̀ ìbá fi í sílẹ̀.A camel cannot carry your luggage, you should've left it.
    1. (transitive) to exalt
      Ẹ bá mi gbé Jésù ga.Exalt Jesus with me.
    2. to take; to transport
      Ẹ jẹ́ a gbé e yẹ̀ wò.Let's take it into consideration.
      gbé àpò yìí sí yàrá ìyá ẹ.Come and take this bag to your mum's room.
      Dáńfó yẹn ń gbé èèyàn lọ sí MuṣinThat Danfo is transporting people to Mushin
    3. to put
      Gbé fóònù sórí tébù.Put the phone on the table.
      Gbé dígí ẹ sójú, kí o lè kà á dáadáa.Put on your glasses so you can read it well
    4. (transitive) to overcome; to overpower
      Wárápá gbé Ṣadé.Ṣadé had epilepsy. (literally, “Epilepsy overcame Ṣadé”)
      Oorun ti gbé e lọ.She's fast asleep. (literally, “Sleep has overcome her.”)
    5. to marry
      Àpọ́n ṣì ni o, kò ì tíì gbé ìyàwó.He's still single o, he hasn't yet married a bride.
      Synonym: fẹ́
Usage notes edit
Derived terms edit

Etymology 2 edit

Pronunciation edit

Verb edit

gbé

  1. (intransitive) to live; to inhabit
    Bàbá mi gbé ní Amẹ́ríkà fúngbà díẹ̀.My dad lived in the US for a short while.
    Ilé tí Bọ́lá ń gbé ò tóbi tó.The house Bọ́lá lives in isn't big enough.
    Abíọ́dún ò gbé nílùú Ìbàdàn mọ́, Èkó ló ń gbé.Abiodun doesn't live in Ibadan anymore, she lives in Lagos.
    Àìná gbélé pẹ̀tẹ́ẹ̀sì.Aina lives in a high-rise.
Usage notes edit
  • used with or without the preposition .

Etymology 3 edit

Pronunciation edit

Verb edit

gbè

  1. (transitive) to favor, to support
    Òrìṣà, bí o ò bá lè gbè mí, ṣe mí bí o ti bá miOrisha, if you cannot support me, leave me as you met me.
    Òwò kan ò lè gbe gbogbo èèyàn.A single business cannot support everyone.
    Ìṣẹ̀ṣe á gbè wá o!Isese will favor us!
    Iṣẹ́ olùkọ́ ò lè gbè mí.Teaching cannot support me financially.
  2. (intransitive) to be favorable, to be profitable
    Iṣẹ́ náà gbèThis job was profitable for me

Etymology 4 edit

Pronunciation edit

Verb edit

gbè

  1. to sing a refrain or chorus
    orin tí kò ṣòroó dá kò níí ṣòroó gbèA song that is not difficult to sing will not be difficult to sing a refrain for (proverb on easy handling or response)
  2. to echo a song
Usage notes edit
  • gbe when followed by a direct object.
Derived terms edit

Etymology 5 edit

Pronunciation edit

Verb edit

gbè

  1. to be spoiled, to be in an unsatisfactory condition or state
    Synonym: bà jẹ́
    ẹja yìí gbèThis fish has spoiled
Usage notes edit
  • gbe when followed by a direct object.

Etymology 6 edit

Pronunciation edit

Verb edit

gbè

  1. to be next or adjacent to something, to be a successor to something (literally next in line)
    ọmọ yìí jókòó gbèThe child sat next to me
Usage notes edit
  • gbe when followed by a direct object.

Etymology 7 edit

Pronunciation edit

Particle edit

gbé

  1. (syntatic marker)
    Ibẹ̀ la gbé ń ṣeré wa.There is where we play our games.
    Ṣáínà ni wọ́n gbé ṣe é.China is where it's made.
    Níbo lo gbé rà á?Where did you buy it?